Postagens

Jẹ́ ki a ki Eṣu Ẹlẹ́gbára

Imagem
    Ẹ kú dédé àsìkò yìí gbogbo olólùfẹ́ èdè ati À ṣ à Yorùbá. Orúk ọ mi ni Ọ̀ m ọ̀ wé Adelson Adéwalé de Brito ti ọpọ l ọ́ p ọ̀ ènìyàn m ọ̀ sí M ọ̀ wé Adelson tabi Mawo Adelson . Olori ẹ̀ sín ibil ẹ̀ Vodun ti àw ọ n alale wa mú lati iha oòrùn il ẹ̀ aláw ọ̀ si il ẹ̀ Am ẹ́ rika iakoko òwò ẹr ú, ni mi. Ọmọ orílẹ̀ede Brasili ni mi, ṣùgbọ́n, Mo yangan pe iran Ànàgó ni mi. Emi jẹ́ ara ipelẹ̀ akoko ninu iran Ànàgó ti wọn mu wa si orílẹ̀ede yìí laarin ni ọgọ́run mẹ́ta ọdún sẹ́hìn, lasiko òwò ẹrú. À wọn Yorùbá gbàgbọ́ wí pé Olódùmarè ló rán ifá wá láti òde ọ̀run latí wá fi ọgbọ́n rẹ̀ tún ilé ayé ṣe. Ni aye ati j ọ́ , àwọn àgbààgbà Ànàgó lò s ọ wi pé kí ó tó bèrè l ọ d ọ Ifá, a kò gb ọ́ d ọ̀ gbàgbé bèrè àyè lat ọ d ọ E ṣ u Ẹl ẹ́ gbára....  Ẹ́  j ẹ́ ki a ki E ṣ u Ẹl ẹ́ gbára Èṣù Láàlú Ogiri okó Laroye àroógọ Abániwọràn báòrídá Ẹbọra tííjẹ Látọpa Èṣù Ọdàrà onilé orita Agọgọlágọ, agọgọlágọ Alàmọnlamo...